Gẹn 18:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Wò o na, emi ti dawọle e lati ba OLUWA sọ̀rọ: bọya a o ri ogun nibẹ̀. On si wipe, Emi ki yio run u nitori ogun.

Gẹn 18

Gẹn 18:29-33