Gẹn 18:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tun wipe, Jọ̃, ki inu ki o máṣe bi OLUWA, emi o si ma wi: bọya a o ri ọgbọ̀n nibẹ̀. On si wipe, Emi ki yio run u bi mo ba ri ọgbọ̀n nibẹ̀.

Gẹn 18

Gẹn 18:22-33