Gẹn 18:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si ba tirẹ̀ lọ, lojukanna bi o ti ba Abrahamu sọ̀rọ tan; Abrahamu si pada lọ si ibujoko rẹ̀.

Gẹn 18

Gẹn 18:25-33