Timoti Keji 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Oluwa jẹ́ kí ó lè rí àánú rẹ̀ gbà ní ọjọ́ ńlá náà. Iṣẹ́ iranṣẹ tí ó ṣe ní Efesu kò ṣe àjèjì sí ìwọ alára.

Timoti Keji 1

Timoti Keji 1:11-18