Timoti Keji 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ìwọ ọmọ mi, jẹ́ kí oore-ọ̀fẹ́ tí ó wà ninu ìdàpọ̀ pẹlu Kristi Jesu sọ ọ́ di alágbára.

Timoti Keji 2

Timoti Keji 2:1-6