Tẹsalonika Kinni 2:19-20 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Nítorí tí kò bá ṣe ẹ̀yin, ta tún ni ìrètí wa, ayọ̀ wa, ati adé tí a óo máa fi ṣògo níwájú Oluwa wa Jesu nígbà tí ó bá farahàn?

20. Ẹ̀yin ni ògo wa ati ayọ̀ wa.

Tẹsalonika Kinni 2