Tẹsalonika Kinni 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

ati bí ẹ ti ń retí Jesu, Ọmọ rẹ̀, láti ọ̀run wá, ẹni tí a jí dìde ninu òkú, tí ó yọ wá kúrò ninu ibinu tí ń bọ̀.

Tẹsalonika Kinni 1

Tẹsalonika Kinni 1:8-10