Tẹsalonika Kinni 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí tí kò bá ṣe ẹ̀yin, ta tún ni ìrètí wa, ayọ̀ wa, ati adé tí a óo máa fi ṣògo níwájú Oluwa wa Jesu nígbà tí ó bá farahàn?

Tẹsalonika Kinni 2

Tẹsalonika Kinni 2:18-20