Tẹsalonika Kinni 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

A fẹ́ wá sọ́dọ̀ yín. Kì í ṣe ọ̀rọ̀ ẹ̀ẹ̀kan tabi ẹẹmeji ni èmi Paulu ti fẹ́ wá, ṣugbọn Satani dí wa lọ́wọ́.

Tẹsalonika Kinni 2

Tẹsalonika Kinni 2:10-20