Tẹsalonika Keji 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe pé a kò ní ẹ̀tọ́ láti jẹun lọ́dọ̀ yín; ṣugbọn a kò ṣe bẹ́ẹ̀ kí á lè fi ara wa ṣe àpẹẹrẹ fun yín, kí ẹ lè fara wé wa.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:1-10