Tẹsalonika Keji 3:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí a wà lọ́dọ̀ yín, a pàṣẹ fun yín pé bí ẹnikẹ́ni bá kọ̀ tí kò ṣiṣẹ́, ẹ má jẹ́ kí ó jẹun.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:2-17