Tẹsalonika Keji 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí a gbọ́ pé àwọn kan ninu yín ń rìn ségesège, wọn kì í ṣiṣẹ́ rárá, ẹsẹ̀ ni wọ́n fi í máa wọ́lẹ̀ kiri.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:5-17