Tẹsalonika Keji 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

A pàṣẹ fún irú àwọn bẹ́ẹ̀, a tún ń rọ̀ wọ́n ninu Oluwa Jesu Kristi pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́ fún oúnjẹ ti ara wọn.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:6-17