Tẹsalonika Keji 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni a kò jẹ oúnjẹ ẹnikẹ́ni ninu yín lọ́fẹ̀ẹ́. Ṣugbọn ninu làálàá ati ìṣòro ni à ń ṣiṣẹ́ tọ̀sán-tòru, kí á má baà ni ẹnikẹ́ni ninu yín lára.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:5-15