Tẹsalonika Keji 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹ̀yin fúnra yín mọ bí ó ti yẹ kí ẹ ṣe àfarawé wa, nítorí a kò rìn ségesège nígbà tí a wà láàrin yín.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:1-12