Tẹsalonika Keji 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, à ń pàṣẹ fun yín ní orúkọ Oluwa wa Jesu Kristi pé kí ẹ yẹra fún àwọn onigbagbọ tí wọn bá ń rìn ségesège, tí wọn kò tẹ̀lé ẹ̀kọ́ tí ẹ ti kọ́ lọ́dọ̀ wa.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:4-11