Tẹsalonika Keji 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Ẹni Burúkú yìí yóo farahàn pẹlu agbára Èṣù: yóo máa pidán, yóo ṣe iṣẹ́ àmì, yóo ṣe iṣẹ́ ìtànjẹ tí ó yani lẹ́nu.

Tẹsalonika Keji 2

Tẹsalonika Keji 2:8-14