Tẹsalonika Keji 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó bá kúrò lọ́nà tán ni Ọkunrin Burúkú nnì yóo wá farahàn. Ṣugbọn Oluwa Jesu yóo fi èémí ẹnu rẹ̀ pa á, yóo sọ ìfarahàn rẹ̀ di asán.

Tẹsalonika Keji 2

Tẹsalonika Keji 2:1-17