Tẹsalonika Keji 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nǹkan àṣírí kan tíí máa fa rúkèrúdò ti bẹ̀rẹ̀ sí ṣiṣẹ́, ṣugbọn ẹni tí ó ń ká a lọ́wọ́ kò wà, kò ì kúrò lọ́nà.

Tẹsalonika Keji 2

Tẹsalonika Keji 2:1-16