Tẹsalonika Keji 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ nisinsinyii, ẹ mọ ohun tí ó ń ká a lọ́wọ́ kò, tí kò jẹ́ kí ó farahàn títí àkókò rẹ̀ yóo fi tó.

Tẹsalonika Keji 2

Tẹsalonika Keji 2:1-13