Tẹsalonika Keji 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo fi ọ̀nà àrékérekè burúkú lóríṣìíríṣìí tan àwọn ẹni ègbé jẹ, nítorí wọn kò ní ìfẹ́ òtítọ́, tí wọn ìbá fi rí ìgbàlà.

Tẹsalonika Keji 2

Tẹsalonika Keji 2:9-12