Samuẹli Kinni 31:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ará Filistia lé Saulu ati àwọn ọmọ rẹ̀. Wọ́n pa Jonatani ati Abinadabu ati Malikiṣua, àwọn ọmọ Saulu.

Samuẹli Kinni 31

Samuẹli Kinni 31:1-6