Samuẹli Kinni 31:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun náà le fún Saulu gidigidi, àwọn tafàtafà ta á ní ọfà, ó sì farapa lọpọlọpọ.

Samuẹli Kinni 31

Samuẹli Kinni 31:1-5