Samuẹli Kinni 31:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Filistia bá àwọn ọmọ Israẹli jagun ní orí òkè Giliboa. Ọpọlọpọ ninu àwọn ọmọ ogun Israẹli kú, àwọn yòókù sì sá. Saulu ati àwọn ọmọ rẹ̀ pàápàá sá lójú ogun.

Samuẹli Kinni 31

Samuẹli Kinni 31:1-2