Samuẹli Kinni 30:2 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n kó gbogbo obinrin ati àwọn tí wọ́n wà níbẹ̀ lẹ́rú, àtọmọdé, àtàgbà, wọn kò sì pa ẹnikẹ́ni.

Samuẹli Kinni 30

Samuẹli Kinni 30:1-12