Samuẹli Kinni 30:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi ati àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ dé, wọ́n rí i pé wọ́n ti dáná sun ìlú náà, wọ́n sì ti kó àwọn aya wọn ati àwọn ọmọ wọn lọkunrin ati lobinrin lẹ́rú.

Samuẹli Kinni 30

Samuẹli Kinni 30:1-7