Samuẹli Kinni 30:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi ati àwọn ọkunrin rẹ̀ pada dé Sikilagi ní ọjọ́ kẹta, wọ́n rí i pé àwọn ará Amaleki ti gbógun ti Nẹgẹbu ati Sikilagi, wọ́n ṣẹgun Sikilagi, wọ́n sì sun ìlú náà níná;

Samuẹli Kinni 30

Samuẹli Kinni 30:1-7