Samuẹli Kinni 29:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ati àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ bá dìde, wọ́n lọ sí ilẹ̀ Filistini, àwọn ọmọ ogun Filistini sì lọ sí Jesireeli.

Samuẹli Kinni 29

Samuẹli Kinni 29:8-11