Samuẹli Kinni 17:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Filistini náà ṣe ń bọ̀ láti pàdé Dafidi, Dafidi sáré sí ààlà ogun láti pàdé rẹ̀.

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:38-57