Samuẹli Kinni 17:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn eniyan wọnyi yóo sì mọ̀ dájú pé OLUWA kò nílò idà ati ọ̀kọ̀ láti gba eniyan là. Ti OLUWA ni ogun yìí, yóo sì gbé mi borí rẹ̀.”

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:38-51