Samuẹli Kinni 17:49 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi mú òkúta kan jáde láti inú àpò rẹ̀, ó fi kànnàkànnà rẹ̀ ta òkúta náà, òkúta náà wọ agbárí Goliati lọ, ó sì ṣubú lulẹ̀.

Samuẹli Kinni 17

Samuẹli Kinni 17:45-55