Samuẹli Kinni 1:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo wá ya ọmọ náà sọ́tọ̀ fún OLUWA, ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ yóo jẹ́ ti OLUWA.”Lẹ́yìn náà, wọ́n sin OLUWA níbẹ̀.

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:25-28