Samuẹli Kinni 1:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ yìí ni mò ń tọrọ lọ́wọ́ OLUWA, ó sì fún mi ní ohun tí mo bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀.

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:19-28