Samuẹli Kinni 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Hana bá gbadura báyìí pé:“Ọkàn mi kún fún ayọ̀ ninu OLUWA,Ó sọ mí di alágbára;mò ń fi àwọn ọ̀tá mi rẹ́rìn-ín,nítorí mò ń yọ̀ pé OLUWA gbà mí là.

Samuẹli Kinni 2

Samuẹli Kinni 2:1-5