Samuẹli Kinni 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Má rò pé ọ̀kan ninu àwọn oníranù obinrin ni mí. Ninu ìbànújẹ́ ńlá ati àníyàn ni mò ń gbadura yìí.”

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:7-23