Samuẹli Kinni 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Hana dá a lóhùn, pé, “Rárá o, oluwa mi, n kò fẹnu kan ọtí waini tabi ọtí líle. Ìbànújẹ́ ló bá mi, tóbẹ́ẹ̀ tí mo fi ń gbadura, tí mo sì ń tú ọkàn mi jáde fún OLUWA.

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:9-23