Samuẹli Kinni 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Eli bá dá a lóhùn, ó ní, “Máa lọ ní alaafia, Ọlọrun Israẹli yóo fún ọ ní ohun tí ò ń tọrọ lọ́wọ́ rẹ̀.”

Samuẹli Kinni 1

Samuẹli Kinni 1:8-20