Samuẹli Keji 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi ṣe jọba lórí gbogbo Israẹli, ó sì ń ṣe ẹ̀tọ́ ati òdodo sí gbogbo eniyan, nígbà gbogbo.

Samuẹli Keji 8

Samuẹli Keji 8:10-18