Samuẹli Keji 8:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ ibùdó àwọn ọmọ ogun káàkiri ilẹ̀ Edomu, gbogbo àwọn ará Edomu sì ń sin Dafidi. OLUWA fún Dafidi ní ìṣẹ́gun ní gbogbo ibi tí ó lọ.

Samuẹli Keji 8

Samuẹli Keji 8:4-18