Samuẹli Keji 8:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi túbọ̀ di olókìkí sí i nígbà tí ó pada dé, láti ibi tí ó ti lọ pa ẹgbaasan-an (18,000) ninu àwọn ará Edomu, ní Àfonífojì Iyọ̀.

Samuẹli Keji 8

Samuẹli Keji 8:5-18