Samuẹli Keji 8:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu, ọmọ Seruaya ni balogun rẹ̀, Jehoṣafati, ọmọ Ahiludi ni alákòóso gbogbo àwọn ìwé àkọsílẹ̀ rẹ̀.

Samuẹli Keji 8

Samuẹli Keji 8:10-18