Samuẹli Keji 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ mọ́kàn gírí kí ẹ sì ṣe akin; nítorí pé Saulu, oluwa yín ti kú, àwọn eniyan Juda sì ti fi òróró yàn mí gẹ́gẹ́ bí ọba wọn.”

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:4-10