Samuẹli Keji 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí OLUWA fi ìfẹ́ ńlá ati òdodo rẹ̀ hàn fun yín. Èmi náà yóo ṣe yín dáradára, nítorí ohun tí ẹ ṣe yìí.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:1-9