Samuẹli Keji 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Abineri ọmọ Neri, tíí ṣe balogun àwọn ọmọ ogun Saulu, gbé Iṣiboṣẹti ọmọ Saulu sá lọ sí Mahanaimu ní òdìkejì odò Jọdani.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:1-9