Samuẹli Keji 19:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Mẹfiboṣẹti bá dáhùn pé, “Jẹ́ kí Siba máa mú gbogbo rẹ̀, kìkì pé kabiyesi pada dé ilé ní alaafia ti tó fún mi.”

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:24-39