Samuẹli Keji 19:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Basilai ará Gileadi náà wá láti Rogelimu. Ó bá ọba dé odò Jọdani láti sìn ín kọjá odò náà.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:22-35