Samuẹli Keji 19:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba dá a lóhùn pé, “Má wulẹ̀ tún sọ nǹkankan mọ́, mo ti pinnu pé ìwọ ati Siba ni yóo pín gbogbo ogun Saulu.”

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:19-34