Samuẹli Keji 12:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ranṣẹ sí Dafidi láti ròyìn fún un pé, “Mo ti gbógun ti Raba, mo sì ti gba ìlú tí orísun omi wọn wà,

Samuẹli Keji 12

Samuẹli Keji 12:19-31