Samuẹli Keji 12:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo àkókò yìí, Joabu wà níbi tí ó ti gbógun ti Raba, olú ìlú àwọn ará Amoni, ó sì gba ìlú ọba wọn.

Samuẹli Keji 12

Samuẹli Keji 12:17-31