Samuẹli Keji 12:28 BIBELI MIMỌ (BM)

kó àwọn ọmọ ogun yòókù jọ, kí o kọlu ìlú náà, kí o sì gbà á fúnra rẹ. N kò fẹ́ gba ìlú náà kí ògo gbígbà rẹ̀ má baà jẹ́ tèmi.”

Samuẹli Keji 12

Samuẹli Keji 12:26-31